Kronika Keji 26:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Usaya ọba fún gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀ ní apata, ọ̀kọ̀, àṣíborí, ẹ̀wù ihamọra, ọfà, ati òkúta fún kànnàkànnà wọn.

Kronika Keji 26

Kronika Keji 26:4-20