Kronika Keji 25:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n fi ẹṣin gbé òkú rẹ̀ wá sí Jerusalẹmu, wọ́n sì sin ín sí ìlú Dafidi ní ibojì àwọn baba rẹ̀.

Kronika Keji 25

Kronika Keji 25:24-28