Kronika Keji 25:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Àkọsílẹ̀ àwọn nǹkan yòókù tí Amasaya ṣe, láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin, wà ninu ìwé àwọn ọba Juda ati Israẹli.

Kronika Keji 25

Kronika Keji 25:21-28