Kronika Keji 25:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, Jehoaṣi, ọba Israẹli, gòkè lọ, òun ati Amasaya ọba Juda sì kojú ara wọn lójú ogun ní Beti Ṣemeṣi ní ilẹ̀ Juda.

Kronika Keji 25

Kronika Keji 25:20-27