Kronika Keji 25:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Amasaya kó oriṣa àwọn ará Edomu tí ó ṣẹgun wá sílé. Ó kó wọn kalẹ̀, ó ń bọ wọ́n, ó sì ń rúbọ sí wọn.

Kronika Keji 25

Kronika Keji 25:8-17