Kronika Keji 25:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Amasaya fi ìgboyà kó ogun rẹ̀ lọ sí Àfonífojì Iyọ̀, ó sì pa ẹgbaarun (10,000) ninu àwọn ọmọ ogun Seiri.

Kronika Keji 25

Kronika Keji 25:10-19