Kronika Keji 25:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ọdún mẹẹdọgbọn ni Amasaya nígbà tí ó jọba; ó sì wà lórí oyè fún ọdún mọkandinlọgbọn ní Jerusalẹmu. Ìyá rẹ̀ ni Jehoadini ará Jerusalẹmu.

Kronika Keji 25

Kronika Keji 25:1-3