Kronika Keji 24:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí Jehoiada kú, àwọn ìjòyè ní Juda wá kí ọba, wọ́n sì júbà rẹ̀, ó sì gba ìmọ̀ràn wọn.

Kronika Keji 24

Kronika Keji 24:10-26