Kronika Keji 24:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ìjòyè ati gbogbo eniyan fi tayọ̀tayọ̀ mú owó orí wọn wá, wọ́n ń sọ ọ́ sinu àpótí náà títí tí ó fi kún.

Kronika Keji 24

Kronika Keji 24:1-15