Kronika Keji 23:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n lọ káàkiri gbogbo ilẹ̀ Juda, wọ́n lọ kó àwọn Lefi ati àwọn baálé baálé gbogbo ní Israẹli wá sí Jerusalẹmu.

Kronika Keji 23

Kronika Keji 23:1-10