Kronika Keji 23:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní kí àwọn eniyan náà dúró, kí wọn máa ṣọ́ ọba, olukuluku pẹlu ohun ìjà lọ́wọ́. Wọ́n tò láti ìhà gúsù ilé náà títí dé ìhà àríwá, ati ní àyíká pẹpẹ ati ti ilé náà.

Kronika Keji 23

Kronika Keji 23:6-12