Kronika Keji 22:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Joaṣi wà pẹlu wọn níbi tí wọ́n gbé e pamọ́ sí ninu ilé OLUWA fún ọdún mẹfa tí Atalaya fi jọba ní ilẹ̀ náà.

Kronika Keji 22

Kronika Keji 22:6-12