Kronika Keji 22:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Atalaya, ìyá Ahasaya rí i pé ọmọ òun ti kú, ó bẹ̀rẹ̀ sí pa gbogbo ìran ọba ní Juda.

Kronika Keji 22

Kronika Keji 22:1-12