Kronika Keji 21:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó jọba tán, tí ó sì ti fìdí ìjọba rẹ̀ múlẹ̀, ó fi idà pa gbogbo àwọn arakunrin rẹ̀ ati díẹ̀ ninu àwọn olóyè ní Israẹli.

Kronika Keji 21

Kronika Keji 21:1-13