Kronika Keji 21:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó, OLUWA yóo fi àjàkálẹ̀ àrùn ṣe àwọn eniyan rẹ, ati àwọn ọmọ rẹ, ati àwọn aya rẹ ati gbogbo ohun tí o ní.

Kronika Keji 21

Kronika Keji 21:5-20