Kronika Keji 20:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan péjọ láti gbogbo ìlú Juda, wọ́n wá bèèrè ìrànlọ́wọ́ OLUWA.

Kronika Keji 20

Kronika Keji 20:3-6