Kronika Keji 20:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ọkunrin Juda dúró níwájú OLUWA pẹlu àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ wọn, àwọn aya wọn ati àwọn ọmọ wọn.

Kronika Keji 20

Kronika Keji 20:9-22