Kronika Keji 20:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn èyí, àwọn ará Moabu, ati àwọn ará Amoni, ati díẹ̀ ninu àwọn ará Meuni kó ara wọn jọ láti bá Jehoṣafati jagun.

Kronika Keji 20

Kronika Keji 20:1-8