Kronika Keji 2:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni ranṣẹ sí Huramu, ọba Tire pé, “Máa ṣe sí mi gẹ́gẹ́ bí o ti ṣe sí Dafidi, baba mi, tí o kó igi kedari ranṣẹ sí i láti kọ́ ààfin rẹ̀.

Kronika Keji 2

Kronika Keji 2:1-8