Kronika Keji 2:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Huramu, ọba Tire, bá dá èsì lẹta Solomoni pada, ó ní, “OLUWA fẹ́ràn àwọn eniyan rẹ̀, ni ó ṣe fi ọ́ jọba lórí wọn.”

Kronika Keji 2

Kronika Keji 2:8-15