Kronika Keji 19:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Sibẹsibẹ àwọn nǹkankan wà tí o ṣe tí ó dára, o run àwọn ère oriṣa Aṣera ní ilẹ̀ yìí, o sì ti ṣe ọkàn rẹ gírí láti tẹ̀lé Ọlọ́run.”

Kronika Keji 19

Kronika Keji 19:1-11