Kronika Keji 18:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọba mejeeji gúnwà lórí ìtẹ́ wọn, ní ibi ìpakà, ní àbáwọ bodè Samaria, gbogbo àwọn wolii sì bẹ̀rẹ̀ sí sọ àsọtẹ́lẹ̀ níwájú wọn.

Kronika Keji 18

Kronika Keji 18:1-10