Kronika Keji 18:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jehoṣafati bèèrè lọ́wọ́ Ahabu pé, “Ṣé kò sí wolii OLUWA mìíràn mọ́ tí a lè bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀?”

Kronika Keji 18

Kronika Keji 18:1-11