Kronika Keji 18:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Ahabu ọba pàṣẹ pé kí wọ́n mú Mikaya lọ sọ́dọ̀ Amoni, gomina ìlú ati sọ́dọ̀ Joaṣi, ọmọ ọba, kí wọ́n sì sọ fún wọn pé:

Kronika Keji 18

Kronika Keji 18:23-29