Kronika Keji 18:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni ẹ̀mí kan jáde, ó sì dúró níwájú OLUWA, ó ní, ‘N óo lọ tan Ahabu jẹ.’ OLUWA bá bèèrè pé, ‘Ọgbọ́n wo ni o fẹ́ dá?’

Kronika Keji 18

Kronika Keji 18:14-30