Kronika Keji 18:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba Israẹli wí fún Jehoṣafati pé, “Ṣé o ranti pé mo ti sọ pé kò sọ àsọtẹ́lẹ̀ rere fún mi rí? Àsọtẹ́lẹ̀ burúkú nìkan ni òun máa ń sọ.”

Kronika Keji 18

Kronika Keji 18:13-26