Kronika Keji 18:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Mikaya dáhùn pé, “Mo fi orúkọ OLUWA búra pé ohun tí Ọlọrun bá sọ fún mi pé kí n sọ ni n óo sọ.”

Kronika Keji 18

Kronika Keji 18:8-18