Kronika Keji 18:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn wolii yòókù ń sọ bákan náà, wọ́n ń wí pé, “Lọ gbógun ti Ramoti Gileadi, o óo ṣẹgun. OLUWA yóo fi wọ́n lé ọba lọ́wọ́.”

Kronika Keji 18

Kronika Keji 18:8-16