Kronika Keji 18:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jehoṣafati ọba Juda di ọlọ́rọ̀ ati olókìkí, ó fẹ́ ọmọ Ahabu kí ó lè ní àjọṣepọ̀ pẹlu Ahabu.

Kronika Keji 18

Kronika Keji 18:1-2