Kronika Keji 17:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n lọ káàkiri gbogbo ilẹ̀ Juda pẹlu ìwé òfin lọ́wọ́ wọn, wọ́n ń kọ́ àwọn eniyan.

Kronika Keji 17

Kronika Keji 17:5-16