Kronika Keji 17:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Igbákejì ni Jehosabadi; òun náà ní ọ̀kẹ́ mẹsan-an (180,000) ọmọ ogun tí wọ́n ti dira ogun, lábẹ́ rẹ̀.

Kronika Keji 17

Kronika Keji 17:8-19