Kronika Keji 17:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Olórí ogun kẹta ni Amasaya, ọmọ Sikiri, ẹni tí ó yọ̀ǹda ara rẹ̀ fún iṣẹ́ OLUWA, ó ní ọ̀kẹ́ mẹ́wàá (200,000) akọni ọmọ ogun.

Kronika Keji 17

Kronika Keji 17:13-19