Kronika Keji 16:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Asa bá kó àwọn eniyan jọ jákèjádò Juda, wọ́n lọ kó òkúta ati pákó tí Baaṣa fi ń kọ́ Rama, wọ́n lọ fi kọ́ Geba ati Misipa.

Kronika Keji 16

Kronika Keji 16:1-10