Kronika Keji 16:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, Asa kó fadaka ati wúrà láti ilé ìṣúra ilé OLUWA ati láti ààfin ranṣẹ sí Benhadadi, ọba Siria tí ó ń gbé Damasku, ó ranṣẹ sí i pé:

Kronika Keji 16

Kronika Keji 16:1-4