Kronika Keji 15:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò náà, kò sí ìbàlẹ̀ ọkàn fún àwọn tí wọn ń jáde ati àwọn tí wọ́n ń wọlé, nítorí ìdààmú ńlá dé bá àwọn tí ń gbé ilẹ̀ náà.

Kronika Keji 15

Kronika Keji 15:1-12