Kronika Keji 15:13 BIBELI MIMỌ (BM)

ati pé ẹnikẹ́ni tí kò bá sin OLUWA Ọlọrun Israẹli, ìbáà ṣe àgbà tabi ọmọde, ọkunrin tabi obinrin, pípa ni àwọn yóo pa á.

Kronika Keji 15

Kronika Keji 15:8-18