Kronika Keji 15:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n mú ẹẹdẹgbẹrin (700) mààlúù ati ẹẹdẹgbaarin (7,000) aguntan ninu ìkógun tí wọ́n kó, wọ́n fi rúbọ sí OLUWA Ọlọrun baba wọn.

Kronika Keji 15

Kronika Keji 15:2-19