Kronika Keji 14:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Sera, ará Etiopia, gbógun tì wọ́n pẹlu ẹgbẹrun lọ́nà ẹgbẹrun (1,000,000) ọmọ ogun ati ọọdunrun (300) kẹ̀kẹ́ ogun. Wọ́n sì jagun títí dé Mareṣa.

Kronika Keji 14

Kronika Keji 14:4-15