Kronika Keji 13:5 BIBELI MIMỌ (BM)

ṣé ẹ ẹ̀ mọ̀ pé OLUWA Ọlọrun Israẹli ti fi iyọ̀ bá Dafidi dá majẹmu ayérayé pé àtìrandíran rẹ̀ ni yóo máa jọba lórí Israẹli títí lae?

Kronika Keji 13

Kronika Keji 13:1-13