Kronika Keji 13:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Abija ati àwọn ọmọ ogun Juda pa àwọn ọmọ ogun Israẹli ní ìpakúpa, tóbẹ́ẹ̀ tí ọ̀kẹ́ mẹẹdọgbọn (500,000) fi kú ninu àwọn akọni ọmọ ogun Israẹli.

Kronika Keji 13

Kronika Keji 13:15-18