Kronika Keji 13:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ogun Juda hó ìhó ogun, bí wọ́n sì ti kígbe ni Ọlọrun ṣẹgun Jeroboamu ati àwọn ọmọ ogun Israẹli fún Abija ati àwọn ọmọ ogun Juda.

Kronika Keji 13

Kronika Keji 13:12-22