Kronika Keji 12:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣiṣaki bá gbógun ti Jerusalẹmu, ó kó gbogbo ìṣúra ilé OLUWA lọ, ati ti ààfin ọba patapata, ati apata wúrà tí Solomoni ṣe.

Kronika Keji 12

Kronika Keji 12:3-16