Kronika Keji 12:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Rehoboamu kú, wọ́n sin ín sí ìlú Dafidi, níbi ibojì àwọn baba rẹ̀. Abija ọmọ rẹ̀ sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Kronika Keji 12

Kronika Keji 12:13-16