Kronika Keji 11:7-11 BIBELI MIMỌ (BM)

7. Betisuri, Soko, ati Adulamu;

8. Gati, Mareṣa, ati Sifi;

9. Adoraimu, Lakiṣi, ati Aseka;

10. Sora, Aijaloni ati Heburoni. Àwọn ni ìlú olódi ní Juda ati Bẹnjamini.

11. Ó tún àwọn ìlú olódi ṣe, wọ́n lágbára, níbẹ̀ ni ó fi àwọn olórí ogun sí, ó sì kó ọpọlọpọ oúnjẹ, epo ati ọtí waini pamọ́ sibẹ.

Kronika Keji 11