Kronika Keji 11:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Nígbà tí Rehoboamu dé Jerusalẹmu, ó kó ọ̀kẹ́ mẹsan-an (180,000) àwọn akọni ọmọ ogun jọ láti inú ẹ̀yà Juda ati Bẹnjamini, láti bá àwọn ọmọ Israẹli jagun, kí ó lè fi ipá gba ìjọba rẹ̀ pada.

2. Ṣugbọn OLUWA sọ fún wolii Ṣemaaya, eniyan Ọlọrun pé,

Kronika Keji 11