Kronika Keji 10:4 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àjàgà tí baba rẹ gbé bọ̀ wá lọ́rùn wúwo, ṣugbọn nisinsinyii, dín wahala tí baba rẹ fi wá ṣe kù, kí o sì sọ àjàgà wa di fúfúyẹ́, a óo sì máa sìn ọ́.”

Kronika Keji 10

Kronika Keji 10:1-12