Kronika Keji 10:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jeroboamu, ọmọ Nebati, gbọ́, ó pada wá láti Ijipti, níbi tí ó ti sá lọ fún Solomoni.

Kronika Keji 10

Kronika Keji 10:1-9