Kronika Keji 10:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àjàgà wúwo ni baba mi gbé bọ̀ yín lọ́rùn, ṣugbọn tèmi yóo tún wúwo ju ti baba mi lọ. Pàṣán ni baba mi fi nà yín, ṣugbọn àkeekèé ni èmi óo fi ta yín.’ ”

Kronika Keji 10

Kronika Keji 10:2-15