Kronika Keji 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Pẹpẹ bàbà tí Besaleli ọmọ Uri, ọmọ Huri ṣe, wà níbẹ̀ níwájú àgọ́ OLUWA. Solomoni ati àwọn eniyan rẹ̀ sin OLUWA níbẹ̀.

Kronika Keji 1

Kronika Keji 1:1-6