Kronika Keji 1:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni ati àwọn tí wọ́n péjọ lọ sí ibi gíga tí ó wà ní Gibeoni, nítorí pé àgọ́ ìpàdé Ọlọrun tí Mose, iranṣẹ OLUWA, pa ninu aginjù wà níbẹ̀.

Kronika Keji 1

Kronika Keji 1:1-13